LYRIC
Ride On (Lyrics) – by Monique Temitope
Jesus Loves You
No Matter Your Sins in the Past
He Gave His Life so You Might Live
Come to Him Today
Lyrics Are Arranged as sang by the Artist
YouTube Video Link is at Bottom of Page
[Verse 1]
Agbára Olórun mbe Níbí
The Power of God is here
Èmí Olórun mbe Níbí
The Spirit of God is here
[Chorus]
Momòpé bímobá képè é,
Óma foùn
Momòpé bímobá kpérè é,
Á sògo.
I know that the Spirit of God
Will cause an Overflow
Ride On, Ride On, Ride On
Èmí Ooh
Ride On, Ride On, Ride On
[Repeat Verse 1]
Agbára Olórun mbe Níbí
The Power of God is here
Èmí Olórun mbe Níbí
The Spirit of God is here
[Chorus]
Momòpé bímobá képè é,
Óma foùn
Momòpé bímobá kpérè é,
Á sògo.
I know that the Spirit of God
Will cause an Overflow
Ride On, Ride On, Ride On
Èmí Ooh
Ride On, Ride On, Ride On
[Ride On (Lyrics) – by Monique Temitope ]
[Verse 2]
Let my Ears belong to you
So all I Hear is you
Let my Heart belong to you
(Let my Heart belong to you)
So all I do is you
Shield me from the Power of sin
Let them got nothing on me.
Holy Spirit, Gbàmí tán
[Chorus]
(Momòpé bímobá képè é,
Óma foùn
Momòpé bímobá kpérè é,
Á sògo.
I know that the Spirit of God
Will cause an Overflow
Ride On, Ride On, Ride On
Èmí Ooh
Ride On, Ride On, Ride On) [x2]
[Spontaneous]
Agbára Olórun mbe láyé mi
Agbára tóh borí ohun gbogbo
Who art thou oh mountain
Níwájú Oba gbogbo ayé
Olúwa tóh pò nípá àti agbára
Òkan soso òrò tí nso gbogbo òrò
Òrò gbénú omi adágún
Òrò gbénú omi òkun ru
Ìjìnlè nlá Atófaratì bí òkè
Mopá tàsetàse L’órúko JÉSÙ Kristì
Egbé oríiyín sókè, èyin
Enu ònà, kí asì gbé e yín sókè èyin
Ilèkùn ayérayé, kí Oba ògo
Kíó wolé wá
Àkóbí nú àwon òkú, òdó àgùntàn
Tíó fèmí rè lé’lè fún wa
Olùdámòràn, igi òkìkí,
àpáta aìí dìgbòlù, òkè táò l’esí
Òjìjí àti ìmólè
YouTube Video
Please Rate this Lyrics by Clicking the STARS below
[kkstarratings]
Ride On (Lyrics) – by Monique Temitope
Also click to Follow US on FaceBook, InstaGram, and Twitter
END
Please Add a comment below if you have any suggestions
Thank you & God Bless you!
The Lyrics are the property and Copyright of the Original Owners
Lyrics here are For Personal and Educational Purpose only!
Comments are off this post